Jump to content

Abdel Moneim Madbouly

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Abdel Moneim Madbouly
عبدالمنعم مدبولي
Abdel Moneim Madbouly in 2006
Ọjọ́ìbí(1921-12-28)Oṣù Kejìlá 28, 1921
Cairo, Egypt
AláìsíJuly 9, 2006(2006-07-09) (ọmọ ọdún 84)
Cairo, Egypt
Iṣẹ́Actor, Playwright
Ìgbà iṣẹ́1949–2005

Abdel Moneim Madbouly (Lárúbáwá: عبد المنعم مدبولي‎, ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1921 – ọjọ́ kẹsàn-án oṣù keje ọdún 2006) jẹ́ òṣeré àti aláwàdà ọmọ orílẹ̀ ède a Íjíptì.[1][2]

A bí Madbouly sí Cairo, ó sì bẹ̀rẹ̀ isẹ́ òṣeré nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún méje, ó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣiṣẹ́ òṣeré lẹ́yìn ìgbà tí bàbá rẹ̀ kú tí ìdílé rẹ̀ sì nílò owó. Ó padà darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣeré Fatma Rushdi kí ó tó tún darapọ̀ mọ́ ile eré George Abyad.[3]

Madbouly kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ere Íjíptì àti Arab

Àtòjọ àwọn eré tí ó ti kópa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • In Al-Hawa Sawa: 1951
  • My Mom and Me: 1957
  • Me and My Heart: 1957
  • Love Festival: 1958
  • Between Heaven and Earth: 1959
  • Heignonne: 1960
  • Take Me With You: 1965
  • Love for All: 1965
  • Kill Me Please: 1965
  • In Summer We Must Love: 1974

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Egypt Today. "Opiate of the Masses". Archived from the original on 2006-06-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. The Daily Star. "ABDEL MONEIM MADBOULY, RENOWNED EGYPTIAN COMEDIAN, DIES AT 85". Archived from the original on 2007-03-12.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. III., Lentz, Harris M. (2007). Obituaries In the performing arts, 2006 : film, television, radio, theatre, dance, music, cartoons and pop culture. Jefferson, N.C.: McFarland & Co. pp. 222. ISBN 9780786452118. OCLC 320461299.