Abdelmadjid Tebboune

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Abdelmadjid Tebboune
عبد المجيد تبون
Abdelmadjid Tebboune in 2019
8th President of Algeria
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
19 December 2019
Alákóso ÀgbàSabri Boukadoum (Acting)
Abdelaziz Djerad
AsíwájúAbdelaziz Bouteflika
16th Prime Minister of Algeria
In office
25 May 2017 – 15 August 2017
ÀàrẹAbdelaziz Bouteflika
AsíwájúAbdelmalek Sellal
Arọ́pòAhmed Ouyahia
Minister of Defence
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
19 December 2019
AsíwájúAhmed Gaid Salah (as Deputy Minister of Defense)
Abdelaziz Bouteflika
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí17 Oṣù Kọkànlá 1945 (1945-11-17) (ọmọ ọdún 78)
Mécheria, Algeria

Abdelmadjid Tebboune (Lárúbáwá: عبد المجيد تبون‎; ọjọ́ìbí 17 November 1945) ni olóṣèlú ará Algeria tó jẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ pé òhun ni Ààrẹ ilẹ̀ Algeria láti December 2019. Ó rọ́pò Ààrẹ Abdelaziz Bouteflika àti Arọ́pò Olórí Orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀ Abdelkader Bensalah. Tẹ́ltẹ́lẹ̀, òhun ló jẹ́ Alákósò Àgbà ilẹ̀ Algeria láti May 2017 di August 2017. Bákannáà, ó tún jẹ́ tẹ́lẹ̀ Alákóso Ètò Ilé láti 2001 di 2002 fún ọdún kan àti ní ẹ̀kan si láti 2012 di 2017 fún ọdún 5.[1]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]