Abdelmajid Lamriss
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 12 Oṣù Kejì 1959 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Morocco | ||
Ìga | 1.70 m (5 ft 7 in) | ||
Playing position | Defender (association football) | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
FAR Rabat | |||
National team | |||
1982-1989 | Morocco national football team | 47 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Abdelmajid Lamriss tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejì, ọdún 1959 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá tó jẹ́ defender fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè Morocco.[1][2]
Àṣèyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Abdelmajid ṣeré fún FAR Rabat. Eléré náà ṣeré fún Cup FIFA Àgbáyé ní ọdún 1986[3][4][5].