Abdul Hai Arifi
Àdàkọ:Use Pakistani English Àdàkọ:Infobox office holder Abdul Hai Arifi (1898–27 March 1986) jé òmòwé mùsùlùmí omo ilè Pakistani àti olùtóni Sufi ti ìlànà Chishti order. Ó jé omo èyìn Ashraf Ali Thanwi. Ó se ìtèjáde àwon ìwé bíi Uswah Rasool-e-Akram àti Ikú àti ogún. Ó s'isé gégé bíi ààre ti Darul Uloom Karachi .fún bíi odún méwà.
Arifi jé akékò jáde ti ilé-èkó Muhammadan Anglo-Oriental College àti ti University of Lucknow. Ó se isé agbejórò l'àárín odún 1926 àti 1935, àti èkó ìtójú àìsàn nípasè ohun kékèèké homeopathy láti odún 1936 títí ti o fi fi aye sí'lè ni ojó ketàdínlógbòn, osù keta odún 1986. Àwon akékò rè kan ni Sufism ni Muhammad Taqi Usmani àti Muhammad Rafi Usmani.
Ìgbésí ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Abdul Hai Arifi ni odún 1898 ni United Provinces of British India.[1] Ó jade ni ilé-ìwé girama Muhammadan Anglo-Oriental College ní odún 1923 ti ó sì gba oyè LLB degree láti ilé-èkó giga University of Lucknow. Ó se isé agbejórò l'àárín odún 1926 àti 1935.[1] Ó fi isé náà sí'lè ti ó sì lo ko isé Homeopathy ni odún 1936. Ó se isé dókítà homeopathy títí ó fi mi èémí ìgbèyìn.[2] Ó sì ti ni àjosepò pèlú Ashraf Ali Thanwi láti odún 1923, tí ó sì di "murid" re ní odún 1927. Thanwi fun ní àkóso ní ìlànà ètò ti Chishti order ni odún 1935.[2]
Arifi jé omo egbé ìsàkóso ti Darul Uloom Karachi tí ó sì di adarí dípò Muhammad Shafi Deobandi gégé bíi ààre Darul Uloom Karachi ti ó sì s'isé sin ilé-èkó ìmò èsìn fun bíi odún méwàá títí ó fí fi ayé sí'lè.[3] ó fi ayé sí'lè ni ojó ketàdínlógbòn osù keta, odún 1986.[4] Muhammad Taqi Usmani ni ó darí àdúrà ìsìnkú re tí Muhammad Zia-ul-Haq àti Jahan Dad Khan [5] sí wà ní'bè. Won sin-ín sí inú ité-òkú ti Darul Uloom Karachi.[6] Ara àwon omo l'éyìn rè ni Muhammad Taqi Usmani[7] àti Muhammad Rafi Usmani.[8]
Isé ìwé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Arifi se àgbéjáde àwon ìwé bíi:[9]
- Uswah Rasool-e-Akram
- Death and Inheritance
- Ashraf Ali Thanvi, life & works
- The Islamic way in death: an authentic and comprehensive handbook of rules, and conduct in the event of death among Muslim
- Maʼās̲ir-i Ḥakīmulummat : irshādāt va ifādāt
- K̲h̲avātīn ke sharʻī aḥkām
- Fihrist-i taʼlīfāt-i Ḥakīmulummat
- Bahādur Yār Jang Akādmī kā taʻāruf
Àsesílè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Muhammad Rafi Usmani wrote Mere murshid Ḥaẓrat-i ʻĀrifī[8] and Sayyid Riyazuddin wrote Ārif Billāh Ḥaz̤rat Ḍākṭar Muḥammad ʻAbdulhaʼī: savāniḥ ḥayāt va taʻlīmāt.[10]
Wo eyí náà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Citations
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Parvez 2008, p. 161.
- ↑ 2.0 2.1 Parvez 2008, p. 162.
- ↑ Usmani 2014, p. 71.
- ↑ Sana'ullah Saad Shuja'abadi 2015, p. 221.
- ↑ Sana'ullah Saad Shuja'abadi 2015, p. 228.
- ↑ Parvez 2008, p. 163.
- ↑ "Profile of Muhammad Taqi Usmani on Muslim500". muslim500.com. Retrieved 25 December 2020.
- ↑ 8.0 8.1 Usmani, Muhammad Rafi. Mere Murshid Hazrat-e-Aarifi. OCLC 1045663631. https://www.worldcat.org/oclc/1045663631. Retrieved 25 December 2020.
- ↑ "Abdul Hai Arifi on WorldCat". worldcat.org. WorldCat. Retrieved 25 December 2020.
- ↑ Sayyid Riyāz̤uddīn. ʻĀrif Billāh Ḥaz̤rat Ḍākṭar Muḥammad ʻAbdulhaʼī: savāniḥ ḥayāt va taʻlīmāt. OCLC 36204814. https://www.worldcat.org/oclc/36204814. Retrieved 25 December 2020.
Ìwé ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Sana'ullah Saad Shuja'abadi, Abu Muhammad (2015). "Hadhrat Mawlāna Dr Abdul Hai Arifi" (in Urdu). Ulama-e-Deoband Ke Aakhri Lamhaat. Saharanpur: Maktaba Rasheediya. pp. 221–228.
- Àdàkọ:Cite thesis
- Usmani, Muhammad Rafi (2014). Mere Murshid Hazrat Arifi. Karachi: Idaratul Ma'arif.