Abel Olúwáfẹ́mi Dòsùmú

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Abel Olúwáfẹ́mi Dòsùmú
Ọjọ́ìbíOṣòdì, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́
 • Olórin Ìyìnrere
 • Olùkọ orin
 • òṣèré
Ìgbà iṣẹ́1994–present

Abel Olúwáfẹ́mi Dòsùmú, ni gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Mega 99, ni ó jẹ́ olórin ìyìnrere àti Jùjú, olùkọ orin akọrin àti ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. [1][2][3]

Ìbẹ̀rẹ̀ Ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Abel ní agbègbè Oṣòdì, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[4] Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Ọlábísí Ọnàbánjọ, tí ó sì gba oyè àkọ́kọ́ nínú ẹ̀kọ́ accountancy.[5] Abel dá ẹgbẹ́ akọrin tí ó pè ní ẹgbẹ́ akọrin ti Mega 9'9, ní ọdún 1994.[6] Àwo orin tí ó gbé Mega 99 yọ síta ni ó pè ní Ìyá mi tí ó kọ ní ọdún 1998, àti àwo mìíràn tí ó pè ní Àdúrà tí ó gbé jáde ní ọdún 2000, tí ó dì tún gbé òmíràn jásmde ní í ọdún 2004 tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní Owó àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[7][8]

Àwọn Àwo orin rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Ìyá mi (1998)
 • Àdúrà (2000)
 • Owó (2003)
 • Ọ̀nà Àrà (2006)
 • Má sunkún mọ́ (2008)
 • Ìdúpẹ́ (2010)
 • Má bẹ̀rù (2013)
 • Ẹ máajó Ẹ máayọ̀ (2014).

Àwọn Ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. "Mega 99 shows class at Opelope Anointing bash". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 15 March 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 2. Our Reporter. "Atorise, Mega 99 thrill at Apata’s album launch". The Nation. Retrieved 15 March 2015. 
 3. "Lavish praises to God for 2012". Daily Independent, Nigerian Newspaper. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 15 March 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 4. "Juju thrives on quality beats – Mega 99". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 15 March 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 5. "Musician, Mega 99 unveil new album". News Nigeria. Retrieved 15 March 2015. 
 6. Latestnigeriannews. "Juju thrives on quality beats ' Mega 99". Latest Nigerian News. Retrieved 15 March 2015. 
 7. "In Fear Not, Mega 99 sings a new song". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 15 March 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 8. "Licking honey, Mega 99 sings victory song". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 15 March 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)