Aberdeen

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Aberdeen
Aiberdeen
Obar Dheathain
Marischal College from Broadhill
Nickname(s): Granite City, Oil Capital of Europe, Silver City
Olùgbé
 - Iye àpapọ̀ Urban area -

184,788[1] (2,001 census)
est. 192,080[2] (2,006)
inc. Cove Bay & Dyce
Local Authority -

est. 202,370[3] (2,005)
 Ìṣúpọ̀ olùgbé 1,089/km2 (2,819/sq mi)
Ibiìtakùn aberdeencity.gov.uk

Ìlú nlá kan nìyí ní ìlà-oòrùn àríwá ilè Scotland. Ara Káúntì (County) Aberdeenshire ni ó wà télè. Láti osù kárùn-ún odún 1975 ni ó ti di ara Grampian. Wón máa n pe Aberdeen ní ‘granite city’. Ó ní Yunifásítì kan tí wón dá sílè ní 1494. Aberdeen Angus ni won máa n pe orúko àgùntàn kan tí ó gbajúmò ní Aberdeen. Àwon ará ìlú Aberdeen ni wón n pè ní Aberdonian.