Aberdeenshire

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Aberdeenshire
Aiberdeenshire
Siorrachd Obar Dheathain
Location
ScotlandAberdeenshire.png
Geography
Area Ranked 4th
 - Total 6,313 km2 (2,437 sq mi)
 - % Water  ?
Admin HQ Aberdeen
ISO 3166-2 GB-ABD
ONS code 00QB
Demographics
Population [[List of Scottish council areas by population|Ranked Àdàkọ:Scottish council populations]]
 - Total (Àdàkọ:Scottish council populations) Àdàkọ:Scottish council populations
 - Density Àdàkọ:Scottish council populations
Politics
Aberdeenshire Council
http://www.aberdeenshire.gov.uk/
Control Àdàkọ:Scottish council control
MPs
MSPs
Aberdeenshire

Agbègbè kan ní ìlà-oòrùn Scotland ni Aberdeenshire. Ó ní àwo òkè ní apá ìwò-oòrùn rè. Ibi tí ó ga jù níbè ni a n pè ní Cairngorm. Àwon òkè yìí je ojú ní gbèsè. Orí òkè wònyí ni odò Don àti Dee ti sun wá. Ní apá ìlà-oòrùn Aberdenshire, isé àgbè ni ó je wón lógún. Bí wón ti n dáko ni wón n sin nnkan òsìn. Bèbè òkun ibè ní òkúta. Buchan Ness tí ó wà ní Aberdeenshire ni ìlú tí ó kángun jù ní ìlà-oòrùn ilè Scotland. Àwon ìlú tí ó se pàtàkì ní Aberdeenshire ni Aberdeen, Peterhead, fraserburgh, Inverturie, Ballatre àti Huntly. Isé àgbè ni ó wópò jù ní Aberdeenshire. Wón dá ilé-isé eja sílè ní Aberdeen, fraserburgh àti Peterhead. Àwon ènìyàn ti ó wà ní agbègbè yìí ní 1961 jé 298, 503.