Abidina Coomassie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Abidina Coomassie jẹ́ akọ̀ròyìn àti atẹ̀wé-ìròyìn jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ìgbésíayé àti iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Coomassie ni ó dá Today's Communications Ltd sílẹ̀, tí ó ń ṣàtẹ̀jáde ìwé-ìròyìn bí́i defunct Today, ìwé-ìròyìn ojoojúmọ́ ti Abuja mirror àti èdè Hausa, A Yau.[1]

A bí i sí ìdílé Ahmadu Coomassie, tó jẹ́ alábòójútó àti àkọ̀wẹ́ ní apá Àríwá Nàìjíríà. Arákùnrin ló jẹ́ ọ̀gá ọlọ́pá tẹ́lẹ̀, Ibrahim Coomassie. [2] Gẹ́gẹ́ bí oníṣẹ́ ìròyìn, ó bẹ̀rẹ̀ ìṣe rẹ̀ ní Ghana Broadcasting service lásìkò ìjọba Kwame Nkrumah, lẹ́yìn tí ó kúrò ní Ghana, ó dára pọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ Radio FRCN, Kaduna lẹ́yìn náà ó sì ṣe ìròyìn nípa ohun abele Naijiria níbi tó ti bá ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ ológun tí wọn yóò tún gbà òṣèlú àwọn ipa .[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àdàkọ:Cite thesis
  2. 2.0 2.1 "Abidina" (in en). New Spear (Kaduna: Spear Ventures) 1 (1). 1993.