Jump to content

Kwame Nkrumah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kwame Nkrumah
3rd Chairman of the Organization of African Unity
In office
21 October 1965 – 24 February 1966
Arọ́pòJoseph Arthur Ankrah
1st Aare ile Ghana
In office
1 July 1960 – 24 February 1966
Asíwájú(ipo tuntun)
Arọ́pòJoseph Arthur Ankrah
as Chairman of the National Liberation Council
1st Prime Minister of Ghana
In office
6 March 1957 – 1 July 1960
AsíwájúOffice Established
Arọ́pòHimself
as President of Ghana
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1909-09-21)21 Oṣù Kẹ̀sán 1909
Nkroful, Gold Coast
Aláìsí27 April 1972(1972-04-27) (ọmọ ọdún 62)
Bucharest, Romania
Ọmọorílẹ̀-èdèBritish, Ghanaian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúConvention People's Party
(Àwọn) olólùfẹ́Fathia Rizk
Àwọn ọmọFrancis, Gamal, Samia and Sekou
ProfessionLecturer

Kwame Francis Nwia Kofie Nkrumah ((21 September, 1909 - 27 April, 1972) je oloselu ati Alakoso Agba akoko fun orile-ede Ghana lati March 6, 1957 titi di 1 July 1960. Nkrumah je oloselu pataki ni ile Afrika be sini o se ipolongo fun iferan larin gbogbo awon omo Afrika kakiri.