Nana Akufo-Addo
Ìrísí
Nana Akufo-Addo | |
---|---|
Ààrẹ ilẹ̀ Ghánà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 7 January 2017 | |
Vice President | Mahamudu Bawumia |
Asíwájú | John Dramani Mahama |
Minister of Foreign Affairs | |
In office 1 April 2003 – 1 July 2007 | |
Ààrẹ | John Agyekum Kufuor |
Asíwájú | Hackman Owusu-Agyeman |
Arọ́pò | Akwasi Osei-Adjei |
Attorney General of Ghana | |
In office 7 January 2001 – 1 April 2003 | |
Ààrẹ | John Agyekum Kufuor |
Asíwájú | Obed Asamoah |
Arọ́pò | Papa Owusu-Ankomah |
Member of Parliament for Akim Abuakwa South | |
In office 2005–2009 | |
Asíwájú | Constituency established |
Arọ́pò | Samuel Atta Akyea |
Member of Parliament for Abuakwa | |
In office 1997–2004 | |
Asíwájú | Constituency established |
Arọ́pò | Constituency abolished |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | William Addo Dankwa Akufo-Addo 29 Oṣù Kẹta 1944 Accra, Gold Coast (now Ghana) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | New Patriotic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Rebecca Griffiths-Randolph |
Àwọn ọmọ | 5 daughters |
Residence | Jubilee House |
Education | Lancing College New College, Oxford University of Ghana Inns of Court School of Law |
Website | Campaign website |
William Addo Dankwa "Nana" Akufo-Addo ( /æˈkʊfoʊ ɑːˈdoʊ/ a-KUUF-oh-_-ah;[1] ọjọ́ìbí 29 March 1944[2]) ni Ààrẹ ilẹ̀ Ghánà lọ́wọ́lọ́wọ́.[3] Ó ti wà ní ipò yìí láti 7 January 2017.[4] Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ ó siṣẹ́ bíi Agbẹjọ́rò Àgbà ilẹ̀ Ghánà láti 2001 di 2003 àti bíi Alákóso Ọ̀rọ̀ Òkèrè láti 2003 di 2007 lábẹ́ ìjọba Ààrẹ John Kufuor.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "OL Elected President of Ghana". lancingcollege.co.uk. 22 December 2016. Archived from the original on 11 February 2017. Retrieved 9 February 2016.
- ↑ "Nana Addo Dankwa Akufo-Addo". Office of the President, Republic of Ghana. Retrieved 25 July 2019.
- ↑ "COVID-19: Nana Addo joins world leaders in signing People's Vaccine". Citinewsroom - Comprehensive News in Ghana, Current Affairs, Business News , Headlines, Ghana Sports, Entertainment, Politics, Articles, Opinions, Viral Content (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-05-16. Retrieved 2020-05-17.
- ↑ Osei Boakye, Evans (7 January 2017). "Nana Akufo Addo Is the New President for Ghana – Here's His Inauguration Speech". GhanaStar. Archived from the original on 8 January 2017. Retrieved 27 February 2017.
- ↑ "Nana Addo Dankwa Akufo-Addo Profile". GhanaWeb. Archived from the original on 20 December 2016. Retrieved 9 December 2016.