Abimbola Abolarinwa
Ìrísí
Abimbola Abolarinwa | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Abimbola Ayodeji Abolarinwa c. 1979 England, United Kingdom |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006 – present |
Àwọn ọmọ | 2 |
Abímbọ́lá Ayọ̀dèjì Abọ́lárìnwá (tí wọ́n bí ní 1979), jẹ́ oníṣègùn ọmọ Nàìjíríà. Ó jẹ́ Urọ́lọ́jístì obìnrin àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà.[1]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Abímbọ́lá ní ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì, ìlú Ọba (UK) fún ìyà rẹ̀ tí ó jẹ́ agbẹjọ́rò, bàbá rẹ̀ sí jẹ́ ọmọ ógun òfuurufú àti dókítà onísẹ́ abẹ. Abọ́lárìnwá jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ìlọfà, tí ó jẹ́ ọ̀kan lára agbègbè Ìjọba ìbílẹ̀ Òkè Ẹ̀rọ́ ní Ìpínlẹ̀ Kwara. Ó ka ilé ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ni ilé ẹ̀kọ́ ọmọ ógun òfuurufú Nàìjíríà alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní Kaduna, ó ṣi parí ilé ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ ọmọ ógun òfuurufú obìnrin tó wà ní ìlú Jos kí ó tó tẹ̀síwájú láti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmò ìṣègun ní Yunifásítì Ibadan ni ọdún 2004.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Orakpo, Ebele (24 May 2015). "My job is not family friendly —Abolarinwa, Nigeria’s first female urologist". Vanguard News. http://www.vanguardngr.com/2015/05/my-job-is-not-family-friendly-abolarinwa-nigerias-first-female-urologist/. Retrieved 18 July 2016.
- ↑ "LASU VC congratulates Abolarinwa, first Nigerian female Urologist". guardian.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-19. Retrieved 2019-12-19.