Abiodun Abodunde

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Abiodun Abodunde

Oluko litireso ni Abiodun Abodunde ni eka-eko Ede ati Litireso Aafirika, OAU, Ife, Nigeria fun ojo pipe. Ori alo ni pupo ninu awon ise re da le. O sise fun opolopo odun ni eka-eko yii ki o to feyin ti ti o si se alaisi leyin aisan ranpe.