Jump to content

Aboki (orin)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
"Aboki"
Fáìlì:Ice Prince - Aboki.jpg
Single by Ice Prince
from the album Fire of Zamani
Released28 August 2012
Recorded2013
GenreHip hop
Length3:07
LabelChocolate City
Songwriter(s)Panshak Zamani
Producer(s)Chopstix
Ice Prince singles chronology
"Ma'Gyptian (Magician Remix)"
(2012)
"Aboki"
(2012)
"More"
(2012)
Àdàkọ:External music video

"Àbókí" (ìtumọ̀ lédè Hausa: "ọ̀rẹ́") jẹ́ àkọlé orin tí olórin ọmọ Nigeria Ice Prince kọ lọ́dún 2012. Ó jẹ́ olú-orin nínú àwo-orin kejì rẹ̀, Fire of Zamani tí ó ṣe jáde lọ́dún 2013. Atọ́kùn-orin tó gbé orin náà jáde pẹlu orin "More" ni Chopstix.[1] Orin náà gbajúmọ̀ nípò 92 lórí àtẹ orin Afribiz ọgọ́rùn-ún tó gbajúmọ̀ jùlọ.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "New Music: Ice Prince – Aboki | More (Full Version)". Bellanaija. Retrieved 23 October 2013. 
  2. "Afribiz - Top 100". Afribiz. Archived from the original on 29 October 2013. Retrieved 23 October 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)