Abubakar Makwashi
Ìrísí
Abubakar Makwashi | |
---|---|
Member of the House of Representatives | |
In office 1999–2003 | |
Constituency | Bakura/Maradun |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Zamfara State, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Occupation | Politician |
Abubakar Makwashi je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà lati ipinle Zamfara. Won bi ni ojo kejila osu kefa ọdún 1946 ni Ìpínlẹ̀ mfara. Makwashi ṣiṣẹ ni Ile Awọn Aṣoju, Apejọ Orilẹ-ede, ti o nsnsójú àgbègbè Bakura/Maradun lati 1999 si 2003. [1] [2] [3]