Abubakar Tafawa Balewa
Jump to navigation
Jump to search
Abubakar Tafawa Balewa | |
---|---|
![]() | |
Alakoso Agba ile Nàìjíríà | |
In office October 1, 1959 – January 15, 1966 | |
Arọ́pò | None |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1912 Bauchi, Nàìjíríà |
Aláìsí | 15 January, 1966 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Northern People's Congress |
Abubakar Tafawa Balewa (December 1912 – January 15, 1966) je omo orile ede Nàìjíríà, lati apa ariwa ile Nàìjíríà. Balewa je Alakoso Agba (prime minister) akoko fun ile Nàìjíríà ni Igba Oselu Akoko ile Nàìjíríà leyin igba ti Nàìjíríà gba ominira ni odun 1960. Eni ayesi ni kariaye, o gba owo ni orile Afrika gege bi ikan lara awon ti won daba idasile Akojoegbe Okan ara Afrika (Organization of African Unity, OAU).
Igba ewe ati ise-owo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
![]() |
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Abubakar Tafawa Balewa |