Adéjọkẹ́ Làsísì
Ìrísí
Adéjọkẹ́ Làsísì | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Ọmọ Nàìjíríà |
Iṣẹ́ |
|
Gbajúmọ̀ fún |
|
Adéjọkẹ́ Làsísì jẹ́ gbajúmọ̀ aránṣọ, aṣègbè ìmọ́tótó àyíká àti oníṣẹ́-ọ̀nà ọmọ Nàìjíríà.[1] Òun ni olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́, Planet 3R tí wọ́n máa ń tún àlòkù ike àti di ohun èlò tuntun mìíràn.[2][3]
Lọ́dún 2020, Adéjọkẹ́ gba àmìn-ẹ̀yẹ ti MSME of the Year Award,[4][5] an event which was well attended by state governors and ministers.[6]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Adejoke Lasisi spins abandoned Aso Oke into amazing accesories". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-24. Retrieved 2020-09-24.
- ↑ Adeoye, Olusola (2020-07-16). "VP Osinbajo: President Buhari’s financial support for MSMEs very robust". TODAY (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-09-24.
- ↑ "Adejoke Lasisi". F6S. Retrieved 2020-09-24.
- ↑ "MSMEs award winners receive cars, cash after virtual edition". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-21. Retrieved 2020-09-24.
- ↑ "Osinbajo lists support schemes for MSME to survive COVID-19 effects". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-17. Retrieved 2020-09-24.
- ↑ Adeoye, Olusola (2020-07-16). "VP Osinbajo: President Buhari’s financial support for MSMEs very robust". TODAY (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-09-24.