Aderonke Adeola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Adérónkẹ́ Adéolá)
Adérónkẹ́ Adéolá
Ọjọ́ìbíAdérónkẹ́ Adéolá
Èkó, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́Nollywood Olùdarí àti Olùdásílè

Adérónkẹ́ Adéolá jẹ́ olùdarí eré oníse ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà kan, òǹkọ̀tàn, onísòwò nípa oge síse, olùkọ̀tàn àti olùdásílẹ̀. Ó gba ẹ̀bùn UNESCO ní bi ayẹyẹ African Film Festivalní ọdún 2019 fún ìwé ìtàn rẹ́ Àwani . [1] [2] Ó tún jẹ́ òǹkọ̀wé fún ìwé ìròyìn The Guardian àti ThisDay.

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adéolá jẹ́ akẹ́ẹ̀kọ́ jáde ti ẹ̀ka ìtàn. [3] Ó ti ṣiṣẹ́ tẹ́lẹ̀ ní ẹ̀ka ìpolówó ọjà àti ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ní Stanbic IBTC.Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ ní RED TV ṣaájú kí ó tó lọ sínú ṣíṣe eré oníse. [4] Ó jẹ́ amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ olùdásílẹ̀ fún ìdásílẹ̀ ìwé ìtán Half of Yellow Sun èyítí a ṣe ní ẹ̀dà eré oníse. Ó ṣe olùdarí eré oníse ìtàn rẹ̀ àkọ́kọ́ Àwani tí ó jẹ́ kó gba ẹ̀bùn UNESCO ní bi ayẹyẹ African Film Festival ní ọdún 2019 àti ẹ̀bùn àǹfàní ní bi ayẹyẹ Impact documentary Awards ní ọdún 2019. [5] [6]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]