Adéwálé Àyúbà
Ìrísí
Adéwálé Àyúbà (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹfà oṣù karùn-ún ọdún 1966) tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Mr. Johnson jẹ́ gbajúgbajà olórin Fújì ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1]
"Mr. Johnson" túndarí síbí yìí. Fún òmíràn, ẹ wo Mr. Johnson (ìṣojútùú).
Adewale Ayuba | |
---|---|
Ayuba | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Adewale Ayuba |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Mr. Johnson |
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kàrún 1966 Ikenne, Ogun State, Nigeria |
Irú orin | World |
Occupation(s) | Singer-songwriter, drummer, dancer, writer, artist, actor |
Years active | 1983–present |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Before Stardom With… Adewale Ayuba – Punch Newspapers". punchng.com. 2015-12-15. Retrieved 2019-12-05.