Adéwálé Adélékè
Adéwálé Adélékè jẹ́ alágbáàtẹrù orin tí wòn bí ní orílẹ̀ èdè Atlanta ní ìlú Geogia, àmọ́ tí ó jẹ́ ọnọ orílẹ̀ èdè Nàìjìríà ní (ọjọ́ Kọkànlá, Oṣù Kejìlá ọdún 1988), tí ó sì jẹ́ olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ orin HKN, tí ó sì darí padà sí ìkú Èkó ní ọdún 2010.[1]
=== Ìgbésí Ayé rẹ̀ àti iṣẹ́ rẹ̀ === Adéwálé Adékéjè tí wọ́n bí ní Atlanta ní ìlú Geogia, sínú ẹbí ọ̀gbẹ́ni Adédẹjì Adékékè àti ìyá rẹ̀ Grace Ajùnwa ní ọdún 1988, ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n fún gbajúgbajà ọ̀kọ̀rin orílẹ̀ èdè Nàìjìríà Davido. Adéwálé Adélékè gba oyè nínú ìmọ̀ bussines Administration ní ọsún 2010 kí ó tó padà sílé nílé-ẹ̀kọ́ Pacific Union College. Adéwálé wà lára tó ṣe agbátẹrù fún orin àbúrò rẹ́ Davido tó sọọ́ di ìlú-mọ̀ọ́ká tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní ọmọ bàbá olówó., tí ilé iṣẹ HKN Music gbé jàde ní ọdún 2012. Nígbà tí ó di ọdún 2014, wòn fún ilé iṣẹẹ́ HKN Music ni àmìẹ̀yẹ City people Entertainment Award, gẹ́gẹ́ bí ilé-iṣẹ́ agbórin jáde tó pegedé jùlọ ní ọdún 2014. Ní ọdún 5015, wọ́n fi Adéwálé ṣe olùdarí ilé-iṣẹ́ bàbá rẹ̀ Adédẹjì Adéléjè ìyẹ̀n Pacific Energy.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Mohammed, Abisola (2019-01-18). "Chairman HKN, Adewale Adeleke, buys himself a 2019Range Rover". Ghafla! Nigeria. Retrieved 2019-03-14.