Adalu (ounje)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Adalu jẹ ounje kan ti á màn pe ni Asáró ni orilẹ-ede Naijiria ti a hún fí agbado ati ẹwa sè, o de gbajumo laarin awọn Yoruba ati awọn Igbo.

Àdàlú ẹ̀wà àti àgbàdo

Igbaradi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A o se agbado ati ewa lọtọ ki a to da awon mejéjì pápọ . [1] A ó sí fi epo púpa, alubosa, ata ati iyọ si ko le ba dun.

A má n jé Adalu pelú ogede ati eja sisun.

Wo awon eleyi na[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ounje ni ilu Naijiria
  • agbado didun
  • Ewa aganyin, ounje Naijiria miiran ti a hún fí ewa se.

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://guardian.ng/life/how-to-make-adalu-beans-and-corn/