Àwọn èdè Adámáwá-Ubangi
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Adamawa-Ubangi)
Adamawa-Ubangi | |
---|---|
(obsolete) | |
Ìpínká ìyaoríilẹ̀: | West and Central Africa |
Ìyàsọ́tọ̀: | Niger-Kóngò
|
Àwọn ìpín-abẹ́: |
Àwọn èdè Adamawa-Ubangi
Àkójopò àwon ède kan ni yí tí wón tó márùn-ún-dín-lógósàn-án (175). Wón wà ní apá àríwá ààrin gbùngbùn Aáfíríkà lati apá ìlà oòrùn nàìjíríà títí dé ìwò oòrùn Sùdáànù. Omo egbé Náíjá Kongò (Niger-Congo) ni wón. Wón n pè wón ni Ìla-oòrun Adamawá (Adamawa-Eastern) télè. Díè lára àwon èdè tó wà lábé ìpìn yìí ni Banda Gbanja àti Ngbika.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |