Jump to content

Adams decarboxylation

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Adams decarboxylation jẹ́ ìdàpọ̀ ṣiṣẹ́ kẹ́míkà tí ó ní ṣe pẹ̀lú yíyọ ẹgbẹ́ carbonyl kúrò nínú coumarins tí ó ní ẹgbẹ́ carboxylic acid ní ipò kjẹta. A maa ń ṣe íyọ ẹgbẹ́ carbonyl kúrò yìuí kúrò nípasẹ àpòpọ̀ aqueous  ti sodium bisulfite, ooru àti àpòpọ̀ líle ti sodium hydroxide.[1][2][3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Adams, R.; Mathieu, J. (1948). "A New Synthesis of Atranol (2,6-Dihydroxy-4-methylbenzaldehyde) and the Corresponding Cinnamic Acid". J. Amer. Chem. Soc. 70 (6): 2120. doi:10.1021/ja01186a037. 
  2. Adams, R.; Bockstaheler, T.E. (1952). "Preparation and Reactions of o-Hydroxycinnamic Acids and Esters". J. Amer. Chem. Soc. 74 (21): 5346. doi:10.1021/ja01141a038. 
  3. Cramer, F.; Windel, H. (1956). "Über Einschlußverbindungen, X. Mitteil.: Die blauen Jodverbindungen der Cumarine und anderer verwandter Verbindungen". Chem. Ber. 89 (2): 354. doi:10.1002/cber.19560890227.