Jump to content

Adaora Elonu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adaora Elonu
CB Avenida
PositionForward
LeagueLiga Femenina de Baloncesto
Personal information
Born28 Oṣù Kẹrin 1990 (1990-04-28) (ọmọ ọdún 34)
Houston, Texas, United States
NationalityNigerian / American
Listed height6 ft 1 in (1.85 m)
Listed weight165 lb (75 kg)
Career information
High schoolAlief Elsik High School
CollegeTexas A&M Aggies women's basketball
NBA draft2012 / Undrafted
Pro playing career2012–present
Career history
2012–2013Hapoel Galil Elyon
2013–2014Beroil–Ciudad de Burgos
2014–2016CB Conquero
2016–2018CB Avenida
2018Atlanta Dream
2019–2021Uni Girona CB
2021–2022Nadezhda Orenburg
2022–presentCB Avenida
Career highlights and awards

Adaora Elonu jẹ ọkan lara agbabọọlu inu agbọn obinrin ninu Naigiria ti a bini 28, oṣu April ni ọdun 1990 jẹ aburo fun Àkọṣẹmọṣẹ agbààlọlu lobinrin inu agbọn tì orukọ rẹ n jẹ Chinemelu Elonu. Adaora ni asiko yi gbààbọọlu fun CB Avienda[1].

  • Adaora ti gba inu agbọn fun college ni Texas A&M, nibi ti arabinrin naa ti jẹ ninu NCAA championship ni ọdun 2011[2].
  • Adaora ti fi igba kan ko awọn ọdọmọbinrin jọ fun ọjọ kan lori ọrọ inu agbọn gẹgẹbi camp ni ipinlẹ Enugu lati fi ṣe àwari talent làrin awọn ọdọ ni orilẹ ede. Atipe Wọn tì fì arabinrin naa jẹ MVP ninu Idije bọọlu inu àgbọn[3].
  1. https://www.topinfoguide.com/wikipedia/adaora-elonus-biography-fact-career-awards-net-worth-and-life-story-081023[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. https://www.zgr.net/en/people/adaora-elonu/amp
  3. https://www.fiba.basketball/news/reigning-womens-afrobasket-mvp-adaora-elonu-commits-to-nurturing-new-talents-in-nigeria