Adebayo Osinowo
Jump to navigation
Jump to search
Adébáyọ́ Sikiru Òṣínáwọ̀ jẹ́ onìṣòwò àti oníṣẹ́-ìlú Nàìjíríàkan. Ó ti yan wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bí ọmọ ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà láti ìlà Oòrùn Èkó fún odún 2019.[1] [2] [3]