Adebayo Salami

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Adébáyọ̀ Sàlámì tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ọ̀gá Bello (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Kẹ̀sán-án oṣù karùn-ún ọdún 1953) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ ìpínlẹ̀ Kwara lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1][2]

Adébáyọ̀ Sàlámì
Ọjọ́ìbí 9, May 1953
Lagos State, Nigeria
Orílẹ̀-èdè Nigerian
Orúkọ míràn Oga Bello
Ọmọ orílẹ̀-èdè Nigerian
Iṣẹ́ Actor, filmmaker and film director
Years active 1964-present
Relatives Femi Adebayo (son)
Kemi Adebayo (daughter)
Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]