Jump to content

Adelard ará Bath

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Adelard of Bath)
The frontispiece of an Adelard de Bada Latin translation of Euclid's Elements, c. 1309–1316; the oldest surviving Latin translation of the Elements is a 12th century translation by Adelard from an Arabic version.[1]

Adelard ara Bath tabi Adelard de Bada (Latin: Adelardus Bathensis) (c. 1080 – c. 1152) je omowe ara Ilegeesi ni orundun 12th scholar. O gbajumo fun ise akoko re ati fun iyipadaede awon iwe sayensi pataki ni iworawo, itorawo, imoye ati mathimatiki latede Griki ati Larubawa si ede Latin lati atejade Larubawa, latibe ni won ti mu won wa si Apaiwoorun Europe. O keko ni Tours, o soluko fun gba die ni Laon, layin re lo rinajo lo si Apaguusu Italia, Syracuse ni Sicily, ati Antioch ni Asia Kekere. O budo si Bath ni Ilegeesi ni odun 1122.[2] O je eni igba kanna pelu William ara Conches, o si je eni to mo sode eye to si mo fere fan.[3]

  1. Russell, Bertrand. A History of Western Philosophy. p. 212.
  2. There is some uncertainty on the details of his career; see Burnett (1987) and Burnett (1999).
  3. Hannam, James. God's Philosophers. pp66-69.