Ìmòye
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Philosophy)
Ìmòye |
---|
Portal |
Ìmòye (Philosophia; Philosophy) ni igbeka awon isoro gbogbo ati pipilese lori ohun bi iwalaye, imo, iyi, ironu, emi ati ede.[1][2] O yato si awon ona idojuko ibere pipilese (bi Iseawo, itan-abiso tabi awon iseona) nipa ona oniyewo, ati ni gbogbo ona sistemu ati igbokan le re lori iyan alalaye.[3] "Philosophy" (filosofi) wa lati ede Griki φιλοσοφία (philosophia), to tumo si "ife oye".[4][5][6]
Àwọn ẹ̀ka ìmòye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìwọ̀nyí ni àwọn ẹ̀ka ti won je gbigbeka ju lo:
- Oro-adanida ni igbeka eda wiwa ati aye. Awon eka re ni oro-igbeaye and oro-iwalaaye.
- oro-ijinle nje mo eda ati ise imo, atipe boya imo se e se. Ninu re ni ti ri isoro iseiyemeji ati ibasepo larin ooto, igbagbo, ati idalare.
- Iwawiwu, tabi "imoye oniwayiyeni", bere bawo ni eni gbodo se huwa tabi boya iru ibere bahun gan ni idahun. Awon eka re ni oro-iwawiwu, ìṣe iwawiwu, ati imulo iwaiwu. oro iwawiwu nda lori eda ero oniwa, afiwe orisi awon sistemu oniwuwa, boya awon ooto oniwawiwu kedere wa, ati bi iru ooto bayi se le je mimo. Bakanna iwawiwu je jijose mo arowa ijeiwatoyeni. Awon iwe dialogi Plato ti bere mupo iwadi fun itumo idara.
- Imoye olselu ni igbeka ijoba ati ibasepo awon enikookan ati awon agbajo mo orileijoba. O mupo awon ibere nipa idajo, ohun didara, ofin, ini ati awon eto ati ojuse omoilu.
- Oro-ewa da lo ri ewa, ona, igbadun, awon iyi sensory-emotional, ihansi, ati nipa iwu ati italara.
- Ogbon je igbeka awon iru ijiyan afesemule. Lati opin orun 19th, awon onimo mathimatiki bi Frege teju si fifi mathimatiki se ogbon, loni oro nipa ogbon pin si meji: ogbon mathimatiki (formal symbolic logic; ogbon ami-idamo) ati eyi ti a mo loni bi ogbon onimoye.
- Ìmòye ẹ̀mí nda le eda emi ati ibasepo re mo ara, o se pataki nitori ijiyan larin ìṣeẹ̀mí meji ati iseohunaye. Apa imoye yi na tun ni ibasepo mo sayensi oloye.
- Imoye ede n se awari eda, ibere ati ilo ede.
- Imoye esin ni apa imoye to un bere awon ibere nipa esin.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Jenny Teichmann and Katherine C. Evans, Philosophy: A Beginner's Guide (Blackwell Publishing, 1999), p. 1: "Philosophy is a study of problems which are ultimate, abstract and very general. These problems are concerned with the nature of existence, knowledge, morality, reason and human purpose."
- ↑ A.C. Grayling, Philosophy 1: A Guide through the Subject (Oxford University Press, 1998), p. 1: "The aim of philosophical inquiry is to gain insight into questions about knowledge, truth, reason, reality, meaning, mind, and value."
- ↑ Anthony Quinton, in T. Honderich (ed.), The Oxford Companion to Philosophy (Oxford University Press, 1995), p. 666: "Philosophy is rationally critical thinking, of a more or less systematic kind about the general nature of the world (metaphysics or theory of existence), the justification of belief (epistemology or theory of knowledge), and the conduct of life (ethics or theory of value). Each of the three elements in this list has a non-philosophical counterpart, from which it is distinguished by its explicitly rational and critical way of proceeding and by its systematic nature. Everyone has some general conception of the nature of the world in which they live and of their place in it. Metaphysics replaces the unargued assumptions embodied in such a conception with a rational and organized body of beliefs about the world as a whole. Everyone has occasion to doubt and question beliefs, their own or those of others, with more or less success and without any theory of what they are doing. Epistemology seeks by argument to make explicit the rules of correct belief formation. Everyone governs their conduct by directing it to desired or valued ends. Ethics, or moral philosophy, in its most inclusive sense, seeks to articulate, in rationally systematic form, the rules or principles involved."
- ↑ Philosophia, Henry George Liddell, Robert Scott, A Greek-English Lexicon, at Perseus
- ↑ Online Etymology Dictionary
- ↑ The definition of philosophy is: "1.orig., love of, or the search for, wisdom or knowledge 2.theory or logical analysis of the principles underlying conduct, thought, knowledge, and the nature of the universe".lol you actually believe this? this is bs Webster's New World Dictionary (Second College ed.).