Jump to content

Ọgbọ́n

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìmọ̀ Ọgbọ́n je eko lori imudaniloju ati amujade.

Lati ni ogbon je nigba èniyàn ni imo tabi oye, tabi o le so pé lati ni ogbon je nigba èniyàn le se tabi yàn awon ipinnu ti o dara gan. Lati ni ogbon je ohun ti enikan le ni ti o dara gidigan. Ogbon se pataki gan, e lo lati wa Ogbon!