Ìjọba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Government)
Detail from Elihu Vedder, Government (1896). Library of Congress Thomas Jefferson Building, Washington, D.C.

Ìjọba ni ikorajo ninu awujo kan, ile oloselu tabi agbajo to ni ase lati se ati fipase ofin, ilana, itele-ofin.

"Ijoba" ntoka si ijoba abele, isejoba oludalara to le ibile, onibinibi, tabi kariaye.

Ìjọba je "akojoegbe, to n joba lori agbegbe iselu kan",[1] "awon alase ninu awujo",[2] ati elo fun awon alase lati pase lori awujo.[3]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]