Adeniran Ogunsanya College of Education

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adeniran Ogunsanya College of Education
Ẹnu ọ̀nà àbáwọlé Adeniran Ogunsanya College of Education
MottoKnowledge, Culture and Service
Motto in Englishknowledge,culture and service
Established1958
TypePublic
ProvostOjogbon Lafiaji Okuneye Bilikis
LocationOto-Awori, Lagos State, Nigeria
WebsiteOfficial website

Adeniran Ogunsanya College of Education, tí àgékúrú rẹ̀ ń jẹ́ (AOCOED), jé ilé-ẹ̀kó gíga (Higher Education) tí ó wà ní ìlú Ọ̀tọ̀-Àwórì lábẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Ọ̀jọ́, Ìpínlé̀ Èkó.[1] ilé- ẹ̀kọ́ Adéníran Ògúnsànyà ń ṣètò ìmọ̀ ìkọ́ni gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ tí ó sì ń pèsè ìwé ẹ̀rí  'Nigeria Certificate in Education' (NCE) àti ìmọ̀ ìkọ́ni tí ilé-ẹ̀kọ́ àgbà alákọ́kọ́ (undergraduate first degree), pẹ̀lú ìbáṣepọ̀ ilé-ẹ̀kọ́ àgbà ti ìpínlẹ̀ ( Èkìtì State University ) [2]

Ìtàn ilé-ẹ̀kọ́ náà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilé-ẹ̀kọ́ gíga náà tí wọ́n kọ́kọ́ ń pè ní "ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìpínlẹ̀ Èkó" (Lagos State College of Education), ni wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1958 gẹ́gẹ́ bí ilé-ẹ̀kọ́ àwọn olùkọ́ onípele kẹ́ta, tí wọ́n sì kọ́kọ́ gbà àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ó tó Àádọ́sàán (90) ní ọdún àkọ́kọ́. Ní ọdún 1982, wọ́n gbé ilé-ẹ̀kọ́ náà kúrò ní Súrùlérè lọ sí Ọ̀tọ̀-Àwórì, látàrí àìtó àwọn ohun amáyé-dẹrùn ìgbà-lódé àti pípọ̀ tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ń pọ̀ si lọ́dọọdún.

Lára àwọn lààmì-laaka tó ti jáde níbẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Kunle Ajayi
  • Sarah Adebisi Sosan
  • Sanai O. Agunbiade

Awon ile-eko mefa ti o wa ni inu ile-eko giga Adeniran Ogunsanya ni:[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • school of science
  • school of education
  • school of art and social science
  • school of vocational and technical education
  • school of early childhood and primary education
  • school of language

Lára àwọn olùkọ́ tó gbajúmọ̀ níbẹ̀ ni[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Afeez Oyètòrò

Ẹ tún lè wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • List of schools in Lagos
  • List of colleges of education in Nigeria

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "About Us". Archived from the original on 6 August 2015. Retrieved 5 July 2015. 
  2. "EKSU sandwich students warned against cultism". Daily Independent Nigeria. 27 March 2013. Archived from the original on 6 July 2015. Retrieved 5 July 2015. 

Ìjápọ̀ ìta[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]