Jump to content

Adeola Ogunmola Showemimo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Adeola Sowemimo jẹ́ awakọ̀ ọ̀furufú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Adeola bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Sunrise Aviation Academy ní orílẹ̀ èdè Amerika níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ọdún 2011.[1]

Àwọn àṣeyọrí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2019, ó di obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àkọ́kọ́ láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Qatar AirwaysÀàrin ìwọ̀ òórùn àgbáyé, ibí tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣòro ti wà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ obìnrin tí wọ́n fẹ́ di awakọ̀ ojú ọ̀furufú.[2]

Òun tún ni obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti wa ọkọ̀ òfuurufú Boeing 787 Dreamliner fún Qatar Airways.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "name of Gold". cable.ng. 
  2. "Adeola Sowemimo: Living Her Dreams". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-09. Retrieved 2020-05-29. 
  3. "Golden tributes". The cable.ng news.