Adewale Maja-Pearce

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adewale Maja-Pearce
Ọjọ́ìbí1953 (ọmọ ọdún 70–71)
London, England
Ẹ̀kọ́St. Gregory's College, Lagos
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity College of Wales;
SOAS University of London
Iṣẹ́Writer, journalist and literary critic
WebsiteÀdàkọ:Website

Adewale Maja-Pearce (tí a bí ní ọdún 1953) jẹ́ òǹkọ̀wé, akọ̀ròyìn àti lámèyítọ́, tó gbajúgbajà fún àwọn àròkọ rẹ̀. Ó ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé, bíi My Father's Country ní Ọdún 1987 àti The House My Father Built ní ọdún 2014, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé onítàn.

Ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adewale Maja-Pearce ní a bí ní Ilu Lọndọnu, England, sínú ìdílé kan tí wọ́n jẹ́ ọmọ Gẹ̀ẹ́sí àti Yorùbá. Ó dàgbà sí Ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó lọ sí ilé-ìwé St. Gregory, ní Obalende, láti ọdún 1965 wọ 1969.[1] Ó sì padà lọ sí ìlú Britain láti kẹ́kọ̀ọ́ si ní University College of Wales, ní ìlú Swansea (BA, 1972–75), ó sì tún lọ sí School of Oriental and African Studies, tó jẹh London University (1984-86), níbi tí ó ti gboyè Masters nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ nípa Africa. [2]

Ìwé àkọsílẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ni Orilẹ-ede Baba Mi: Irin-ajo Nàìjíríà (William Heinemann, 1987), CreateSpace Independent Publishing Platform, 2011,ISBN 978-1467913973 .
  • Ibusọ melo ni si Babiloni? Aroko Heinemann, Ọdun 1990,ISBN 978-0434441723 .
  • Jijo boju-boju: Awọn onkọwe ara ilu Naijiria ti awọn ọgọrin, Hans Zell Publishers, 1992.ISBN 978-0905450926ISBN 978-0905450926 .
  • Lati Khaki si Agbada: Iwe afọwọkọ fun awọn idibo Kínní, 1999 ni Nigeria, Ẹgbẹ Ominira Ilu, 1999,ISBN 978-9783218895 .
  • Ranti Ken Saro-Wiwa ati Awọn arosọ miiran, Gong Tuntun, 2005,ISBN 978-9783842106 .
  • Ibanujẹ Pataki: JP Clark-Bekederemo ati Ibẹrẹ ti Awọn iwe-kikọ Naijiria ti ode oni ni Gẹẹsi, CreateSpace Independent Publishing Platform, 2013,ISBN 978-1492184553 .
  • Ile ti Baba Mi Kọ, Kachifo Limited, 2014,ISBN 978-9785284218 .

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]