Afam Ogene
Ìrísí
Afam Victor Ogene je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o n ṣiṣẹ gẹgẹbi Aṣoju àgbà ti o n sójú àgbègbè Ogbaru ti Ìpínlẹ̀ Anambra ni Ile-igbimọ Asofin kẹwàá. [1] [2] [3]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.vanguardngr.com/2023/10/lp-rep-member-ogene-wins-at-tribunal-says-its-validation-of-peoples-will/
- ↑ https://www.thisdaylive.com/index.php/2023/04/16/lps-ogene-wins-ogbaru-federal-constituency-poll-in-anambra/
- ↑ https://pmnewsnigeria.com/2023/04/16/afam-ogene-wins-ogbaru-federal-constituency-seat/