Jump to content

Afolayan Musa Moses

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Afolayan Musa Moses (ojoibi 13 August 1956) je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà ati ọmọ ile ìgbìmọ̀ aṣòfin kẹjọ ti o n sójú àgbègbè Oke-Ero ni ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlè Kwara . [1]