Jump to content

African Conservation Centre

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ẹgbẹ́ African Conservation Centre (ACC) jẹ́ ẹgbẹ́ aládàáni kan tí ó wà ní Kenya. Wọ́n dá ẹgbẹ́ náà kalẹ̀ ní ọdún 1995. Ní ọdún 2007, Ford Foundation fún wọn ní owó tó tó US$200,000. Iṣẹ́ wọn ni láti dáàbò bò àwọn ẹranko nínú igbó nípa jíjà fún ìjọba tí ó dà."[1] Ọkàn lára àwọn iṣẹ́ wọn, Shompole Group Ranch."[2] gba àmì-ẹ̀yẹ 2006 Equator Initiative Award.

Wọ́n dá African Conservation Center (ACC) kalẹ̀ ní ara àwọn ọdún 1970s. Ó kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ bi ẹgbẹ́ tí ó ń ṣe ìwádìí nípa bi a tilè dáàbò bo àwọn ẹranko inú igbó. Ní ọdún 1995, ACC fi orúkọ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ilé isé tí kò sí fún èrè. Láti ìgbà náà, ilé isé náà ti ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ àṣeyọrí. Ní ọdún 2012, ACC ṣiṣẹ pẹ̀lú South Rift Association of Landowners.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "African Wildlife & Conservation News - African Wildlife & Conservation News - Environmental Science and Conservation News on South Africa". Conservation Africa News Magazine. 2022-01-22. Archived from the original on 2023-05-05. Retrieved 2023-05-05.  Text "African Wildlife & Conservation News" ignored (help)
  2. "Shompole Group Ranch". africanlatitude.com. 2018-04-25. Archived from the original on 2018-04-25. Retrieved 2023-05-05.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)