African University of Science and Technology
Ìrísí
African University of Science and Technology | |
---|---|
Fáìlì:African Institute of Science and Technology logo.png | |
Established | 2007 |
Type | Private |
President | Azikwe Peter Onwalu (acting) |
Location | Abuja, Nigeria 9°00′04″N 7°25′19″E / 9.001°N 7.422°ECoordinates: 9°00′04″N 7°25′19″E / 9.001°N 7.422°E |
Campus | Urban |
Former names | African Institute of Science and Technology |
Affiliations | Nelson Mandela Institution |
Website | aust.edu.ng |
African University of Science and Technology jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ àkànṣe kọ́mpútà àti ìmọ̀-jíjáde lágbàáyé níbi tí wọ́n ti ń fúnni ní ètò ẹ̀kọ́ àkànṣe àti ọ̀gá káàkiri agbègbè àti ayé gíga ní ìlú Àbújá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ilé-ẹ̀kọ́ náà ni wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 2007 gẹ́gẹ́ bí apá àkọ́kọ́ ti ètò ilé-ẹ̀kọ́ àkànṣe àgbáyé Pan-Africa tí àjọ Nelson Mandela ṣe àlàyé rẹ̀. Ilé-ẹ̀kọ́ náà ń pèsè àwọn ètò ẹ̀kọ́ ọ̀gá ní ẹ̀ka máàrún: Ìmọ́ Computer Science and Management of Information Technology, ìmọ́ Material Science and Engineering, ìmọ́ Petroleum Engineering, ìmọ́ Pure and Applied Mathematics, àti ìmọ́ Space & Aerospace Sciences. Wón sì tún fún nì ní àmì ẹ̀yẹ olùkọ́jáwé ní Public Administration and Public Policy.