Jump to content

African Writers Trust

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
African Writers Trust (AWT)
Fáìlì:African Writers Trust logo.png
Ìdásílẹ̀2009
Purpose/focusLáti sọ àwọn òǹkọ̀wé ni Áfríkà papọ̀
IbùdóPlot 819, Off Kiira Road, KyaliwajjalaNamugongo (P.O. Box 6753), Kampala, Uganda
Websiteafricanwriterstrust.org

African Writers Trust (AWT) jẹ́ ẹgbẹ́ tí wọ́n sàgbékalè ní ọdún 2009 gẹ́gẹ́ bi ẹgbẹ́ "tí ó ń sakitiyan láti so àwọn òǹkọ̀wé ní Áfríkà àti àwùjọ Áfríkà papọ̀ àti láti mú kí wọ́n pín ìmọ̀ láàrin ara wọn."[1]

Olùdásílẹ̀ àti adarí AWT lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Goretti Kyomuhendo, gbajúmọ̀ òǹkọ̀wé tí ó jẹ́ alákòóso àkọ́kọ́ fún FEMRITE – Uganda Women Writers' Association.[2]

African Writers Trust ní àwọn ìgbìmò ìmọ̀ràn tí ó ń darí rẹ̀, àwọn ni (ní ọdún 2017) Zakes Mda, Susan Nalugwa Kiguli, Ayeta Anne Wangusa, Helon Habila, Leila Aboulela, Mildred Barya, àti Aminatta Forna.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "What is African Writers Trust?" Retrieved 24 August 2011.
  2. Lamwaka, Beatrice, "Goretti Kyomuhendo of African Writers Trust" Archived 2011-07-20 at the Wayback Machine., 22 May 2011. Retrieved 24 August 2011.
  3. "Advisory Board", African Writers Trust. Retrieved 24 August 2011.