Èdè Áfríkáánì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Afrikaans)
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Afrikaans
Sísọ ní

Gúúsù Áfríkà South Africa
Namibia Namibia
Bòtswánà Botswana
Lèsóthò

Lesotho
Swaziland Swaziland
Agbègbè Southern Africa
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ est. 6.45 million (first language)
6.75 million (second or third language)
12 to 16 million (basic language knowledge) estimation October 2007Àdàkọ:Citation needed.
Èdè ìbátan
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Èdè oníbiṣẹ́ ní Gúúsù ÁfríkàSouth Africa
Àkóso lọ́wọ́ Die Taalkommissie
(The Language Commission of the South African Academy for Science and Arts)
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1 af
ISO 639-2 afr
ISO 639-3 afr

Àdàkọ:Wiktionary Èdè ìwò oòrùn Jámìnì (a West Germany language) tí ó wáyé láti ara Dóòjì (Dutuh) ni eléyìí tí wón ń so ní Gúsù Aáfíríkà. Àwon tí ó ń so ó tó míhíònù méfà. Wón ń so ó ní Nàmíbíà, màláwì, Zambia àti Zimbabwe. Àwon kan tí ó sì ti se àtìpó lo sí ilè Australia àti Canada náà ń so èdè náà. Wón tún máa ń pa èdè yìí ni kéépú Doòjì (lapa Dutch). Èdè àwon tí ó wá te ilè Gúsù Aáfíríkà dó ní séńtúrì ketàdínlógún (17th century) ni sùgbón ó ti wá yàtò sí èdè Dóòjì (Dutch) ti ilè Úroòpù (Europe) báyìí nítorí èdè àdúgbò kòòkan ti ń wo inú rè. Èdè yìí ni èdè tí ó lé ní ìdajì àwon funfun tí ó dó sí Gúsù Aáfíríkà ń so. Ìdá àádósà n-án àwon tí òbí won jé èyà méjì ni ó sì ń so èdè yìí pèlú. Láti odún 1925 ni won ti ń lo èdè yìí pèlú èdè Gèésì gégé bí èdè ìjoba. Èdè yìí tin í lítírésò. Àkotó Rómáànù ni wón fi ń ko ó.