Jump to content

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Adó-Èkìtì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Agbegbe Ijoba Ibile Ado-Ekiti je ijoba ibile ni Ipinle Ekiti towa ni Nigeria. Ibujoko re wa ni ilu Ado-Ekiti.