Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Nnewi
Ìrísí
Àgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Ńnéwi jẹ́ ọ̀kan lára ìjọba-ìbílẹ̀ mọ̀kànlélógún tí ó wà Ìpínlẹ̀ Anambra ní orílè-èdè Nàìjíríà.[1] Ìlú Ukpor ni Olú-ìlú ìjọba-ìbílẹ̀ Gúúsù Ńnéwi.[2] Wọ́n dá a sílẹ̀ ní ọdún 1991 pẹ̀lú àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mọ̀kànlélógún yòókù.[3] Àwọn olùgbé ìjọba-ìbílẹ̀ náà tó mílíọ́nù kan. Iṣẹ́ ̀agbẹ̀ àti kárà kátà ni àwọn olùgbe ibe yàn laa ayó .Esin igbabo ni esin wa
Àwọn gbajúmọ̀ ìlú tí wọ́n wà ní ìjọba ìbílẹ̀ Gúúsù Ńnewi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Yàtọ̀ sí olú-ìlú ìjọba ìbílẹ̀ náà, àwọn ìlú gbajúmọ̀ tí wọ́n tún wà lábẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Gúúsù Ńnéwi ni; Ekwulumili, Amichi, Azigbo, Unubi, Ezinifite, Osumenyi àti Utuh. [4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Kabir, Olivia (2018-12-21). "Local governments in Anambra state and their towns". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2019-11-16.
- ↑ "Light Of The Nation". Anambra State Government. Archived from the original on 2019-11-16. Retrieved 2019-11-16.
- ↑ "History of Anambra state". Oganiru Anambra. 2019-11-12. Archived from the original on 2019-11-16. Retrieved 2019-11-16.
- ↑ "Nnewi South L.G.A List of towns and villages". Nigeria Zip Codes (in Èdè Ruwanda). Retrieved 2019-11-16.
5. https://www.manpower.com.ng/places/lga/121/nnewi-south
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |