Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Akinyele
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Akinyele)
Akinyele | |||
---|---|---|---|
Coordinates: Coordinates: 7°31′25″N 3°54′53″E / 7.5237°N 3.9147°E | |||
Country | Nigeria | ||
State | Oyo State | ||
Headquarters | Moniya | ||
Government | |||
• Local Government Chairman | Taoheed Jimoh Adedigba (PDP) | ||
Time zone | UTC+1 (WAT) | ||
|
Akinyele jé agbègbè ìjoba ìbílè ní ìpínlè Oyo,orílè èdè Nàíjíríà. Ó jé okan lára àwon ìjoba ìbílè mokànlá tí ó parapò di ìlú Ìbàdàn. Ó wà ní agbègbè Móníyà. Wón dá a sílè ní odún 1976 ó pa ààlà pèlú ìjoba ìbílè Afijio ní apá àríwá,ìjoba ìbílè lagelu si apa ilà oòrùn.
Wón fi so orúko olóògbé Olúbàdàn Isaac Babalola Akinyele.