Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Garki
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Garki)
Garki, Nigeria | |
---|---|
LGA and town | |
Àwòrán ọjà gbogboogbò ti ìlú Garki | |
Nickname(s): Garkin Dirani | |
Coordinates: Coordinates: 12°25′56″N 9°10′52″E / 12.4322°N 9.1812°E | |
Country | Nigeria |
State | Jigawa State |
Government | |
• Local Government Chairman | Mudassir Musa (APC) |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Garki jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ kan ní orílẹ̀-èdè Naijiria, ní ipinle Jigawa. Olú ẹ̀ka rẹ̀ wà ní ìlú Garki. Wọ́n tún máa ń pè é ní Garkin Dirani, èyí tó jẹ́ orúkọ olórí agbègbè náà.
Ó ní ìwọ̀n ìtóbi tó 1,408 km2 àti èrò tó ń lọ bíi 152,233, ìyẹn ní ọdún 2006.
Kóòdù ìfìwéráńṣé agbègbè naà ni 733.[1]
Ìlú Garki ni agbègbè tí wọ́n ti ṣe Garki project, èyí tó jẹ́ iṣẹ́ àkànṣe ti WHO láti mú ìdínkù bá àìsàn tí ẹ̀fọn ń mú wa, ó bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1969 wọ ọdún 1976.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Molineaux, L.; Gramiccia, G. (1980). The Garki Project: Research on the Epidemiology and Control of Malaria in the Sudan Savanna of West Africa. World Health Organization. ISBN 9241560614.