All Progressives Congress

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
All Progressives Congress
National Chairman Adams Oshiomole[1]
Deputy National Chairman for the North Lawal Shuaibu[2]
Deputy National Chairman for the South Olusegun Oni[3]
National Secretary Alhaji Mai Mala Buni
Ìdásílẹ̀ 6 Oṣù Kejì 2013; ọdún 7 sẹ́yìn (2013-02-06)
Ìdàpọ̀ mọ́ ACN
CPC
ANPP
Ibùjúkòó 40 Blantyre Street, off Adetokunbo Ademola Street, Wuse II, Abuja, FCT
Ọ̀rọ̀àbá Progressivism[citation needed]
Social democracyqq1
Economic populism[citation needed]
Ipò olóṣèlú Centre-left[4]
Ìbáṣepọ̀ akáríayé Socialist International (consultative)
Official colours              Green, white, blue
     Red (customary)
Seats in the House Àdàkọ:Composition bar
Seats in the Senate Àdàkọ:Composition bar
Governorships Àdàkọ:Composition bar
Ibiìtakùn
Ìṣèlú ilẹ̀ Nigeria

All Progressives Congress tí àlékúrú rẹ̀ ń jẹ́' APC jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú tí ó ń ṣe ìjọba lọ́wọ́́lọ́wọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Kí ó tó di ọdún 2015, ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò ni APC jẹ́, ṣùgbọ́n wọ́n di ẹgbẹ́ òṣèlú-ṣèjọba lẹ́yìn ìdìbò tí ó gbé Ààrẹ Muhammadu Buhari wọlé lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú náà.[5] Wọ́n dá ẹgbẹ́ yìí sílẹ̀ lọ́dún 2013.[6] Adams Oshiomhole ni Alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC.[7]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Oshiomhole Emerges APC National Chairman Unopposed". Sahara Reporters. 2018-06-23. Retrieved 11 September 2018. 
  2. admin. "Senator Lawal Shuaibu - APC All Progressives Congress". apc.com.ng. Archived from the original on 22 March 2018. Retrieved 21 March 2018. 
  3. admin. "Olusegun Oni - APC All Progressives Congress". apc.com.ng. Archived from the original on 22 March 2018. Retrieved 21 March 2018. 
  4. Campbell, John (9 October 2018). "The Stage Is Set for Nigeria's February 2019 Presidential Election". Council on Foreign Relations. Retrieved 4 March 2019. 
  5. "Elections Result « INEC Nigeria". inecnigeria.org. 2015-04-14. Archived from the original on 2015-04-14. Retrieved 2019-12-08. 
  6. "The Merger This Time!". P.M. News. 2013-02-13. Retrieved 2019-12-08. 
  7. "Oshiomhole Emerges APC National Chairman Unopposed". Sahara Reporters. 2018-06-23. Retrieved 2019-12-08.