Jump to content

Labour Party (Nigeria)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Labour Party
National ChairmanJulius Abure
National SecretaryAlh. Umar Farouk Ibrahim
Slogan"Forward Ever"
Ìdásílẹ̀2002; ọdún 22 sẹ́yìn (2002)
AṣíwájúParty for Social Democracy (PSD)
IbùjúkòóNo. 29 Okeagbe Street, Off Samuel Ladoke Akintola Boulevard, Garki II, Abuja
Ọ̀rọ̀àbáSocial democracy
Official colorsRed and green
Seats in the HouseÀdàkọ:Composition bar
Seats in the SenateÀdàkọ:Composition bar
GovernorshipsÀdàkọ:Composition bar
Seats in State Houses of AssemblyÀdàkọ:Composition bar
Ibiìtakùn
labourparty.com.ng

Ẹgbẹ́ Labour Party (LP) jẹ́ ẹgbẹ́-òṣèlú lórílẹ̀-èdè Nigeria. Wọ́n dá a sílẹ̀ lọ́dún 2002. Ní ìbẹ̀rẹ̀, Party for Social Democracy, (PSD), kí wọ́n tó yíi padà sí Labour Party. Wọ́n dá ẹgbẹ́ yìí sílẹ̀ èròǹgbà-ìmọ̀ ìṣèjọba aṣègbè-àwùjọ. Èròǹgbà wọn ni láti ṣe ìgbélárugẹ ètò-ìṣèjọba oríòjorí àti ìdájọ́ òdodo láwùjo pẹ̀lú ìṣọ̀kan.[1]

Lọ́jọ́ 27 oṣù Karùn-ún ọdún 2022, àwọn ọmọ ẹgbẹ́ yìí bẹ̀rẹ̀ sí ní pọ̀ sí í nígbà tí gómìnà-àná tí Ìpínlẹ̀ Anambra, Peter Òbí dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ náà láti ẹgbẹ́ òsèlú People's Democratic Party, PDP, láti díje dupò Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nigeria lọ́dún 2023. [2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Komolafe, Kayode (2022-06-01). "Labour Party in New Colour?". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-03. 
  2. "Peter Obi joins Labour Party | Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-05-27. Retrieved 2022-06-03.