Ẹgbẹ́ Olóṣèlúaráìlú àwọn Aráàlù (Nàìjíríà)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
People's Democratic Party
Chairman Uche Secondus
Akọ̀wé Àgbà Abubakar Kawu Baraje
Ìdásílẹ̀ 1998 (1998)
Ibùjúkòó Wadata Plaza, Michael Okpara Way, Wuse, Abuja
Ọ̀rọ̀àbá Moderate
Official colours Green, white, red
Ibiìtakùn
PDP, INEC
PDP, Yar' adua 2007
Ìṣèlú ilẹ̀ Nigeria

People's Democratic Party|PDP jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1998. Àwọn ni ọmọ ẹgbẹ́ wọn ṣe ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà títí di ọdún 2015 kí ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress tó gbàjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; Olúṣẹ̀gún Ọbásanjọ́, Umaru Musa Yar'Adua àti Goodluck Jonathan ni ẹgbẹ́ yìí jẹ kí ẹgbẹ́ APC tó dà wọ́n lágbo nù lọ́dún 2015, tí Ààrẹ Muhammadu Buhari tí ẹgbẹ́ APC fi wọlé gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]