Goodluck Jonathan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Goodluck Jonathan
Goodluck Jonathan World Economic Forum 2013.jpg
President of Nigeria
In office
5 May 2010 – 29 May 2015
Vice President Namadi Sambo
Asíwájú Umaru Yar'Adua
Arọ́pò Muhammadu Buhari
Vice President of Nigeria
Lórí àga
29 May 2007 – 5 May 2010
Ààrẹ Umaru Yar'Adua
Asíwájú Atiku Abubakar
Arọ́pò Namadi Sambo
Governor of Bayelsa
Lórí àga
9 December 2005 – 29 May 2007
Asíwájú Diepreye Alamieyeseigha
Arọ́pò Timipre Sylva
Personal details
Ọjọ́ìbí Goodluck Ebele Azikiwe Jonathan
20 Oṣù Kọkànlá 1957 (1957-11-20) (ọmọ ọdún 62)
Ogbia, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlu People's Democratic Party
Spouse(s) Patience Faka
Alma mater University of Port Harcourt

Goodluck Ebele Jonathan (ojoibi 20 November 1957)[1] je oloselu omo ile Naijiria ati Aare orile-ede Naijiria lati May 6, 2010. Ohun ni Igbakeji Aare ile Naijiria si Aare Umaru Musa Yar'Adua ki o to dipo fun gege bi Adipo Aare ni 9 February, 2010 nitori aisan to de Yar'Adua mole. Leyin ti Yar'Adua ku ni May 5, 2010, Jonathan di Aare. Bakanna tele o tun je Gomina ipinle Bayelsa larin 9 December 2005 ati 28 May 2007 ati Igbakeji Gomina ipinle Bayelsa.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Lawson Heyford, "Jonathan: A Colossus at 49", The Source (Lagos), 11 December 2006