Ojo Maduekwe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ojo Maduekwe
Minister of Transportation
In office
2001–2003
AsíwájúKema Chikwe
Arọ́pòPrecious Sekibo
Foreign Minister of Nigeria
In office
July 26, 2007 – March 17, 2010
AsíwájúJoy Ogwu
Arọ́pòHenry Odein Ajumogobia
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1945-05-06)Oṣù Kàrún 6, 1945
Abia State, Nigeria
AláìsíJune 29, 2016(2016-06-29) (ọmọ ọdún 71)
Abuja, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party

Chief Ojo Maduekwe /θj/ (tí wọ́n bí ní ọjọ́ 6, 1945, tó sì ṣaláìsí ní ọjọ́ June 29, 2016) jẹ́ olóṣèlú orílè-èdè Nàìjíríà láti ẹ̀yà Igbo, ní Ohafia, Ipinle Abia.

Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní University of Nigeria, Nsukka, ó sì gboyè ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ òfin ní ọdún 1972.[1]

Iṣẹ́ òṣèlú tó yàn láàyò[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ṣọ́n yàn án sípò Mínísítà tó ń rí sí ọ̀rọ̀ ilẹ́ òkèèrè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríàní ọjọ July 26, 2007 láti ọwọ́ President Umaru Yar'Adua.[2] Ó kúrò lórí oyè ní oṣù March 2010 lásìkò tí Ààrẹ Goodluck Jonathan wó ẹgbẹ́ náà kalẹ̀.[3] Òun ni National Secretary ti ẹgbẹ́ olóṣèlú Peoples Democratic Party (PDP). Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i igbákejì olùdarí fún ìpolongo ìdìbò ti ọdún 2011 lábẹ́ Goodluck/Sambo. Wọ́n yàn án fún SGF, àmọ́ wọ́n padà mu sílẹ̀ nítorí ìkùnsínú àwọn ènìyàn láti apa Ìlà-oòrun ilẹ̀ Nàìjíríà.

Tẹ̀lẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n yan Maduekwe gẹ́gẹ́ bí iMínísítà tó ń rí sí àṣà àti Tourism gba ọwọ́ ààrẹ Olusegun Obasanjo ní ọdún1999.[4]

Ọ̀rọ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Nigerian Transport Minister Out Spoken On Bike". Vanguard. July 2001. Archived from the original on 2010-06-13. Retrieved 2010-02-08.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Nigerian president names three to Cabinet energy posts, warns against graft", Associated Press (International Herald Tribune), July 26, 2007.
  3. Daniel Idonor (17 March 2010). "Jonathan Sacks Ministers". Vanguard. Retrieved 2010-04-14. 
  4. Seyi Oduyela (January 1, 2006). "State of The Nation: Countdown To 2007". Dawodu. Retrieved 2010-02-08. 
  5. Patrick Henry (January 7, 2007). "Political Rumors and Surprises: The Dust has Cleared". NgEX!. Archived from the original on 2010-01-13. Retrieved 2010-02-08. 
Àdàkọ:S-ppoÀdàkọ:S-end
Preceded by
Vincent Ogbulafor
National Secretary of the PDP
2003 – 2016
Succeeded by
Vacant

Àdàkọ:Authority control

Àdàkọ:Nigeria-politician-stub