Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti President of Nigeria)
Jump to navigation Jump to search
President the
Federal Republic of Nigeria
Seal of the President of Nigeria.svg
Incumbent
Muhammadu Buhari

since 29 May 2015
Appointer Ètò ìdìbò
Term length Ọdún mẹ́rin tí ó sì lè gbé àpótí lẹ́ẹ̀kansi
Inaugural holder Nnamdi Azikiwe
Formation 1 October 1963

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ olórí̀ ijọba àti olórí Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàíjíríà tí ó gorí àléfà pèlú ìbò. Orúkọ iṣé-ọba rẹ̀ jẹ́ Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnìra Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Aláṣẹ Pátápátá Ilé-iṣẹ́ Ológun ilẹ̀ Nàìjíría.

Itan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nigbati Naijiria di ile apapo oselu olominira ni odun 1963 larin Awon Orile-ede Ajoni, o diwo mo ona ijoba igbimo asofin ti o jogun lat'owo ile Britani. Nnamdi Azikiwe ti o je Gomina Agba nigbana di Aare, ipo to je fun ayeye, nigbati ti Abubakar Tafawa Balewa si di ipo Alakoso Agba mu.

Àkójọ àwọn Olórí Ìjọba Ológun àti Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Láti Ọdún 1963-1966[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà (1963-1966)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oruko Ojoibi-Ojoalaisi Igba ijoba bere Igba ijoba pari Egbe oloselu
Nnamdi Azikiwe 1904 - 1996 1 October 1963 16 January 1966 (deposed) NCNC

Àwọn Olórí Ìjọba Ológun orílẹ̀ èdè Nàìjíríà (1966-1979)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nàìjíríà

Àyọkà yí jẹ́ ìkan nínú:
Ìṣèlú àti ìjọba ilẹ̀
NàìjíríàOther countries · Atlas
Politics portal
Oruko Ojoibi-Ojoalaisi Igba ijoba bere Igba ijoba pari Egbe oloselu
Ogagun Agba Johnson Aguiyi-Ironsi 1924 - 1966 16 January 1966 29 July 1966 (deposed and murdered Ologun
Ogagun Yakubu Gowon 1934 - 1 August 1966 29 July 1975 (deposed) Ologun
Ogagun Murtala Mohammed 1938 - 1976 29 July 1975 13 February 1976 (assassinated) Ologun
Ogagun Olusegun Obasanjo (1st time) 1937 - 13 February 1976 1 October 1979 Ologun

Ààrẹ orílẹ̀ Nàìjíríà (1979-1983)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọrúkọ Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí Ìgbà bẹ̀rẹ̀ Ìgbà parí Ẹgbẹ́ olóṣèlú
Shehu Shagari 1925 - 2018 1 October 1979 31 December 1983 (deposed) NPN

Alaga Igbimo Ologun Togajulo ile Naijiria (1983-1985)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọrúkọ Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí Ìgbà bẹ̀rẹ̀ Ìgbà parí Ẹgbẹ́ olóṣèlú
Muhammadu Buhari 1942 - 31 December 1983 August 27 1985 (deposed) Ologun

Aare Igbimo Ile-ise Ologun ile Naijiria (1985-1993)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọrúkọ Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí Ìgbà bẹ̀rẹ̀ Ìgbà parí Ẹgbẹ́ olóṣèlú
General Ibrahim Babangida 1941 - 27 August 1985 26 August 1993 (resigned) Ologun

Olórí orílẹ̀-èdè ìjọba fìdíhẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (1993)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọrúkọ Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí Ìgbà bẹ̀rẹ̀ Ìgbà parí Ẹgbẹ́ olóṣèlú
Ernest Adegunle Oladeinde Shonekan 1936 - 26 August 1993 17 November 1993 (deposed) Koni

Alaga Igbimo Ijoba Igba Pato ile Naijiria (1993-1999)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọrúkọ Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí Ìgbà bẹ̀rẹ̀ Ìgbà parí Ẹgbẹ́ olóṣèlú
General Sani Abacha 1943 - 1998 17 November 1993 8 June 1997 (died in office) Ologun
General Abdulsalami Abubakar 1942 - 8 June 1998 29 May 1999 Ologun

Àwọn Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (1999-Oni)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọrúkọ Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí Ìgbà bẹ̀rẹ̀ Ìgbà parí Ẹgbẹ́ olóṣèlú
Olusegun Obasanjo (2nd time) 1937 - 29 May 1999 29 May 2007 PDP
Umaru Yar'Adua 1951 - 2010 29 May 2007 5 May 2010 (died in office) PDP
Goodluck Jonathan 1957 - 5 May 2010 29 May 2015 PDP
Muhammadu Buhari 1942- 29 May 2015 APC
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

E tun wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]