Shehu Shagari

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Shehu Shagari
Shagaricropped.jpg
6th Aare ile Naijiria
Lórí àga
1 October, 1979 – 31 December, 1983
Vice President Alex Ekwueme
Asíwájú Olusegun Obasanjo
Arọ́pò Muhammadu Buhari
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí Oṣù Kejì 25, 1925 (1925-02-25) (ọmọ ọdún 92)
Shagari, Ipinle Sokoto, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlú National Party of Nigeria
Ẹ̀sìn Musulumi (Sunni)

Shehu Usman Aliyu Shagari (bíi ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọn Oṣù karún Ọdún 1925) jẹ̣́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lati ọjọ́ kínni oṣù Kẹwá ọdún 1979 títí di ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kejìlá ọdún 1983 nígbàtí àwọn ológun gba ìjọba.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]