Johnson Aguiyi-Ironsi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ogagun-Agba Johnson Aguiyi-Ironsi
AguiyiIronsi.JPG
2ji Aare ile Naijiria (ekeji)
In office
January 16, 1966 – July 29, 1966
AsíwájúNnamdi Azikiwe
Arọ́pòYakubu Gowon
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1924-03-03)Oṣù Kẹta 3, 1924
Umuahia, Abia State, Nigeria
AláìsíJuly 29, 1966(1966-07-29) (ọmọ ọdún 42)
Lalupon, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúkòsí (iṣẹ́ ológun)

Johnson Thomas Umunnakwe Aguiyi-Ironsi (March 3, 1924 - 29 July, 1966) je ologun omo orile-ede Naijiria. Leyin ti ologun gba ijoba ni 15 January, 1966, Aguiyi-Ironsi di Olori Orile-ede Naijiria titi di 29 July, 1966 nigbati won dote si ijoba re ti won si pa.

Igba ewe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bi ni ilu Umuahia to wa ni Ipinle Abia loni ni ojo keta osu keta odun 1924 fun Mazi ati Ezugo Aguiyi. Nigba to pe omo odun mejo Aguiyi-Ironsi ko lo si odo egbon re obinrin Anyamma eni to je aya Theophilius Johnson to je osise asoju ijoba fun ile Sierra Leone ni Umuahia. Nigbato to omo odun mejidinlogun Ironsi bo si ise ologun Naijiria botilejepe egbon re lodi si.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]